B'A O KuAropin ni tomo eniyan, e ma ro mi pin. Aropin ni teyin eniyan, e ye ro eda pin mo. Ki lo se yin, eyin omo eniyan, te fi ro pe ko ni le dara mo. Se ti gbagbe ni palanu lEledumare, ti o gbagbe omo eni kankan, Aropin ni teyin enia, e ma ro mi pin. Aropin ni teyin eniyan, e ye ro eda pin mo. Igba kan ri nigba kan, won so pe ko sona fun mi. Bi won ba npo lorire o nigba yen, emi ki i le yoju. Sugbon lojo oni o idunnu ti subu layo funmi. Bi won ba nbere olorire ladugbo mi niseyin o, odo mi ni won nmu won o bo segbo. Bawo ni mo se laluyo o, ohun meta pere lo na mi. Mo tepa mose, mo si ngbadura, mo ko lati ro ra mi pin. Oro mi ti ja sope o, o ja sope o. Oro mi ti ja sope o, o ja sope o. E wa gbo nosia mi gbogbo omo adarihurun. Belomiran ba nro e pin, ma ma ro ra re pinn. Mo joko mo ronu mo consider oro ara mi. Pe boba je nigba to le mo mi. Ki nti lo pokun so, abi ki nti lo be somi. Igba tire mi wa de o, igbo ni iba ti ba mi. Ki nti lo pokun so, abi ki nti lo bee somi. I gba tire mi wa de o, ibo ni iba ti bami. Baba ma je nrogun ogo de emi pin. tori emi o ba won wa bee ni mi o ni ba won lo. Taya tokooo, tomotomoooo, Tebi tara e taka iku sonu. Awa o ni bawon kuu iku aitojo. Ohun yohun ko de ba o ore wa, iku ko ni solution, ma para reeee. Awa o ni bawon kuu iku aitojo. Ba o ku ise o tan oree wa, ediye ti o ku o si ma jagbadoooo. Awa o ni bawon kuu iku aitojo. O si ma dara o, o si ma korin pe, aye ope yo o baba seun aye ope yoo Oluwa seun yes keee Baba mo mope mi wa, ewa bami gbe gba Ope. Igba ti mo roo bi mo se bere ti mo fi wa de level ti mo wa yi, oro ki sibe ojareeee aaaa Baba mo mope mi wa, ewa bami gbe gba Ope. Oluwa seun bi o seun o. O see o Ose Oseun Oluwa seun tenikan o le se.Mo ni Jesu seun bi o seun o ninu ayee waaa. O see o Ose Oseun Oluwa seun tenikan o le se. Ohun tegbegberun eniyan parapo lati se ti won o lee see Jesu nikansoso ohun lo da seeee. Mo ni Jesu seun bi o seun o e wi mi mo fe gbooo. O see o Ose Oseun Oluwa seun tenikan o le se. Irawo Owuro Omo Maria, nibiti won so pe ko sona oni ki nkalo ona mbe nibe fun mii. Mo lo seun ati oseun ooo O see o Ose Oseun Oluwa seun tenikan o le se. O tan mbi o tan o, mo lo tan mbi o tan o, ohun taraye so pe ko sese yen, iyanu ti won so pe ko le kan mi mo baba ti see fun mi o O tan mbi o tan o, mo lo tan mbi o tan o, ohun taraye so pe ko sese yen, iyanu ti won so pe ko le kan mi mo baba ti see fun mi o, Alaanu lOlorun mi, Oloore Ofe nii, iyanu ti won ro pe ko le kan mi mo, baba ti se fun mi o. O tan mbi o tan o, mo lo tan mbi o tan o, ohun taraye so pe ko sese yen, iyanu ti won so pe ko le kan mi mo baba ti see fun mi o Baba mi ko jade nile won nriI lode, ibere latoopin Opin latibere, Alagbada ina, Alawotele oorun. Oobajuwon Alagbara kanrikesee. O nfina ja ninu ile, be lo ntu ara oko lara. Baba mi asoro fijalo.Oloye Eekerin ninu ina, to tun nfese rin loori omi. Okansoso Oro, Okaka Oro ti nka satani laya, Alase kiki Oro, Oro gbenu omo eniyan fohun O fohun safefe iji gboran siI lenu. Oba mi ara oto, baba mi Oluaye. Alale ile to ju gbogbo irumole loooo.E lulu e korin e je a gbOluwa ga, E lulu e korin e je a gbOluwa ga, Olorun mi ga a be o mo Olorun tobi a be o mo ni e lulu e korin e je a gbOluwa gaaa.